Àìsáyà 41:29 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 29 Wò ó! Gbogbo wọn jẹ́ ẹ̀tàn.* Iṣẹ́ wọn kò já mọ́ nǹkan kan. Afẹ́fẹ́ lásán àti ohun tí kò sí rárá ni àwọn ère onírin* wọn.+
29 Wò ó! Gbogbo wọn jẹ́ ẹ̀tàn.* Iṣẹ́ wọn kò já mọ́ nǹkan kan. Afẹ́fẹ́ lásán àti ohun tí kò sí rárá ni àwọn ère onírin* wọn.+