Diutarónómì 32:9 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 9 Torí àwọn èèyàn Jèhófà ni ìpín+ rẹ̀;Jékọ́bù ni ogún+ rẹ̀. Sáàmù 135:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Jáà ti yan Jékọ́bù fún ara rẹ̀,Ó ti yan Ísírẹ́lì ṣe ohun ìní rẹ̀ pàtàkì.*+