-
Jeremáyà 4:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Àjálù lórí àjálù ni ìròyìn tí à ń gbọ́,
Nítorí pé wọ́n ti pa gbogbo ilẹ̀ náà run.
Lójijì, wọ́n pa àgọ́ mi run,
Ní ìṣẹ́jú kan, wọ́n pa aṣọ àgọ́ mi run.+
-