Àìsáyà 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Ìwọ Ísírẹ́lì, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn rẹPọ̀ bí iyanrìn òkun,Àṣẹ́kù wọn nìkan ló máa pa dà.+ A ti pinnu ìparun ráúráú,+Ìdájọ́ òdodo* sì máa bò wọ́n.+
22 Ìwọ Ísírẹ́lì, bó tiẹ̀ jẹ́ pé àwọn èèyàn rẹPọ̀ bí iyanrìn òkun,Àṣẹ́kù wọn nìkan ló máa pa dà.+ A ti pinnu ìparun ráúráú,+Ìdájọ́ òdodo* sì máa bò wọ́n.+