-
2 Àwọn Ọba 22:16Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
16 “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Màá mú àjálù bá ibí yìí àti àwọn tó ń gbé ibẹ̀, gbogbo ohun tó wà nínú ìwé tí ọba Júdà kà ni màá ṣe.+
-
-
Jeremáyà 6:19Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
19 Ẹ fetí sílẹ̀, ẹ̀yin orílẹ̀-èdè ayé!
-
-
Ìsíkíẹ́lì 7:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 “Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: ‘Wò ó! Àjálù, àjálù kan tó ṣàrà ọ̀tọ̀ ń bọ̀.+
-