Sáàmù 139:1, 2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 139 Jèhófà, o ti yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, o sì mọ̀ mí.+2 O mọ ìgbà tí mo bá jókòó àti ìgbà tí mo bá dìde.+ Láti ibi tó jìnnà réré, o mọ ohun tí mò ń rò.+
139 Jèhófà, o ti yẹ̀ mí wò látòkè délẹ̀, o sì mọ̀ mí.+2 O mọ ìgbà tí mo bá jókòó àti ìgbà tí mo bá dìde.+ Láti ibi tó jìnnà réré, o mọ ohun tí mò ń rò.+