Ìdárò 2:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Wo bí Jèhófà ṣe fi ìkùukùu* ìbínú rẹ̀ bo ọmọbìnrin Síónì! Ó ti ju ẹwà Ísírẹ́lì láti òkè ọ̀run sí ilẹ̀ ayé.+ Kò sì rántí àpótí ìtìsẹ̀+ rẹ̀ ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀.
2 Wo bí Jèhófà ṣe fi ìkùukùu* ìbínú rẹ̀ bo ọmọbìnrin Síónì! Ó ti ju ẹwà Ísírẹ́lì láti òkè ọ̀run sí ilẹ̀ ayé.+ Kò sì rántí àpótí ìtìsẹ̀+ rẹ̀ ní ọjọ́ ìbínú rẹ̀.