ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • 2 Àwọn Ọba 24:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 Lẹ́yìn náà, Jèhófà bẹ̀rẹ̀ sí í rán àwọn akónilẹ́rù* àwọn ará Kálídíà,+ ti àwọn ará Síríà, ti àwọn ọmọ Móábù àti ti àwọn ọmọ Ámónì sí i. Ó ń rán wọn sí Júdà léraléra láti pa á run, gẹ́gẹ́ bí ọ̀rọ̀ tí Jèhófà+ gbẹnu àwọn ìránṣẹ́ rẹ̀, wòlíì sọ.

  • Ìsíkíẹ́lì 16:37
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 37 torí náà, èmi yóò kó gbogbo àwọn olólùfẹ́ rẹ tí ẹ jọ gbádùn ara yín jọ, gbogbo àwọn tí o fẹ́ràn àti àwọn tí o kórìíra. Màá kó wọn jọ láti ibi gbogbo kí wọ́n lè bá ọ jà, màá sì tú ọ sí ìhòòhò lójú wọn, wọ́n á sì rí ìhòòhò rẹ.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́