Jeremáyà 9:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+ Jeremáyà 10:22 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 22 Fetí sílẹ̀! Ìròyìn kan ń bọ̀! Ariwo rúkèrúdò láti ilẹ̀ àríwá,+Láti sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, ibùgbé àwọn ajáko.*+
11 Màá sọ Jerúsálẹ́mù di òkìtì òkúta,+ ibùgbé àwọn ajáko,*+Màá sì sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, tí ẹnikẹ́ni kò ní gbé ibẹ̀.+
22 Fetí sílẹ̀! Ìròyìn kan ń bọ̀! Ariwo rúkèrúdò láti ilẹ̀ àríwá,+Láti sọ àwọn ìlú Júdà di ahoro, ibùgbé àwọn ajáko.*+