-
Míkà 6:15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
15 Wàá fún irúgbìn, àmọ́ o ò ní ká a.
Wàá tẹ ólífì, àmọ́ o ò ní lo òróró rẹ̀;
Wàá ṣe wáìnì tuntun, àmọ́ o ò ní rí wáìnì mu.+
-
15 Wàá fún irúgbìn, àmọ́ o ò ní ká a.
Wàá tẹ ólífì, àmọ́ o ò ní lo òróró rẹ̀;
Wàá ṣe wáìnì tuntun, àmọ́ o ò ní rí wáìnì mu.+