-
Jeremáyà 6:21Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
21 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí:
“Wò ó, màá fi àwọn ohun ìkọ̀sẹ̀ sí iwájú àwọn èèyàn yìí,
Wọ́n á sì mú wọn kọsẹ̀,
Àwọn bàbá àti àwọn ọmọ,
Aládùúgbò àti ọ̀rẹ́,
Gbogbo wọn yóò sì ṣègbé.”+
-