-
Ìsíkíẹ́lì 24:14Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 Èmi Jèhófà ti sọ̀rọ̀. Yóò rí bẹ́ẹ̀. Ohun tí mo sọ ni màá ṣe, mi ò ní kẹ́dùn, mi ò sì ní pèrò dà.+ Wọ́n á fi ìwà àti ìṣe rẹ dá ọ lẹ́jọ́,’ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí.”
-