ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Jeremáyà 5:19
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 19 Tí wọ́n bá sì béèrè pé, ‘Kí ló dé tí Jèhófà Ọlọ́run wa fi ṣe gbogbo nǹkan yìí sí wa?’ kí o sọ fún wọn pé, ‘Bí ẹ ṣe fi mí sílẹ̀ láti sin ọlọ́run àjèjì ní ilẹ̀ yín, bẹ́ẹ̀ ni ẹ ó sin àwọn àjèjì ní ilẹ̀ kan tí kì í ṣe tiyín.’”+

  • Jeremáyà 16:10, 11
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 10 “Nígbà tí o bá sọ gbogbo ọ̀rọ̀ yìí fún àwọn èèyàn yìí, wọ́n á béèrè lọ́wọ́ rẹ pé, ‘Kí nìdí tí Jèhófà fi sọ pé kí gbogbo àjálù ńlá yìí dé bá wa? Kí la ṣe, ẹ̀ṣẹ̀ wo la ṣẹ Jèhófà Ọlọ́run wa?’+ 11 Kí o fún wọn lésì pé, ‘“Nítorí pé àwọn baba ńlá yín fi mí sílẹ̀,”+ ni Jèhófà wí, “wọ́n ń tẹ̀ lé àwọn ọlọ́run míì, wọ́n ń sìn wọ́n, wọ́n sì ń forí balẹ̀ fún wọn.+ Ńṣe ni wọ́n fi mí sílẹ̀, wọn kò sì pa òfin mi mọ́.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́