Jẹ́nẹ́sísì 25:13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 13 Orúkọ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì nìyí, orúkọ wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé tí wọ́n ti wá: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+ Sáàmù 120:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Mo gbé, nítorí mo jẹ́ àjèjì ní Méṣékì!+ Mò ń gbé láàárín àwọn àgọ́ Kídárì.+ Jeremáyà 49:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Sí Kídárì+ àti àwọn ìjọba Hásórì, àwọn tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa run, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ dìde, ẹ gòkè lọ sí Kídárì,Kí ẹ sì pa àwọn ọmọ Ìlà Oòrùn.
13 Orúkọ àwọn ọmọ Íṣímáẹ́lì nìyí, orúkọ wọn gẹ́gẹ́ bí ìdílé tí wọ́n ti wá: Àkọ́bí Íṣímáẹ́lì ni Nébáótì,+ lẹ́yìn náà ó bí Kídárì,+ Ádíbéélì, Míbúsámù,+
28 Sí Kídárì+ àti àwọn ìjọba Hásórì, àwọn tí Nebukadinésárì* ọba Bábílónì pa run, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ dìde, ẹ gòkè lọ sí Kídárì,Kí ẹ sì pa àwọn ọmọ Ìlà Oòrùn.