Jeremáyà 2:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 ‘Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti ṣẹ́ àjàgà rẹ sí wẹ́wẹ́+Mo sì já ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ rẹ. Ṣùgbọ́n, o sọ pé: “Mi ò ní sìn ọ́,” Torí pé orí gbogbo òkè àti abẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀+ Ni o nà gbalaja sí, tí ò ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+ Ìsíkíẹ́lì 16:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 “‘Àmọ́ ẹwà rẹ mú kí o bẹ̀rẹ̀ sí í jọ ara rẹ lójú,+ o sì di aṣẹ́wó torí òkìkí rẹ ti kàn káàkiri.+ Gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ lo bá ṣèṣekúṣe,+ ẹwà rẹ sì di tiwọn.
20 ‘Tipẹ́tipẹ́ ni mo ti ṣẹ́ àjàgà rẹ sí wẹ́wẹ́+Mo sì já ṣẹkẹ́ṣẹkẹ̀ rẹ. Ṣùgbọ́n, o sọ pé: “Mi ò ní sìn ọ́,” Torí pé orí gbogbo òkè àti abẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀+ Ni o nà gbalaja sí, tí ò ń ṣe iṣẹ́ aṣẹ́wó.+
15 “‘Àmọ́ ẹwà rẹ mú kí o bẹ̀rẹ̀ sí í jọ ara rẹ lójú,+ o sì di aṣẹ́wó torí òkìkí rẹ ti kàn káàkiri.+ Gbogbo àwọn tó ń kọjá lọ lo bá ṣèṣekúṣe,+ ẹwà rẹ sì di tiwọn.