-
Léfítíkù 26:20Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
20 Lásán ni ẹ máa lo gbogbo agbára yín, torí ilẹ̀ yín kò ní mú èso rẹ̀ jáde,+ àwọn igi ilẹ̀ yín kò sì ní so èso.
-
-
Diutarónómì 28:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
23 Ojú ọ̀run tó wà lókè orí rẹ máa di bàbà, ilẹ̀ tó sì wà lábẹ́ ẹsẹ̀ rẹ máa di irin.+
-