- 
	                        
            
            Jóṣúà 7:9Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        9 Tí àwọn ọmọ Kénáánì àti gbogbo àwọn tó ń gbé ilẹ̀ náà bá gbọ́ nípa rẹ̀, wọ́n á yí wa ká, wọ́n á sì pa orúkọ wa rẹ́ kúrò ní ayé, kí lo máa wá ṣe nípa orúkọ ńlá rẹ?”+ 
 
- 
                                        
- 
	                        
            
            Sáàmù 25:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        11 Nítorí orúkọ rẹ, Jèhófà,+ Dárí ẹ̀ṣẹ̀ mi jì mí, bó tilẹ̀ jẹ́ pé ó pọ̀. 
 
-