Sáàmù 106:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Àmọ́, ó gbà wọ́n sílẹ̀ nítorí orúkọ rẹ̀,+Kí wọ́n lè mọ bí agbára rẹ̀ ṣe pọ̀ tó.+ Sáàmù 106:21 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 21 Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run,+ Olùgbàlà wọn,Ẹni tó ṣe àwọn ohun ńlá ní Íjíbítì,+ Àìsáyà 45:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lóòótọ́, Ọlọ́run tó ń fi ara rẹ̀ pa mọ́ ni ọ́,Ìwọ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, Olùgbàlà.+
21 Wọ́n gbàgbé Ọlọ́run,+ Olùgbàlà wọn,Ẹni tó ṣe àwọn ohun ńlá ní Íjíbítì,+ Àìsáyà 45:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Lóòótọ́, Ọlọ́run tó ń fi ara rẹ̀ pa mọ́ ni ọ́,Ìwọ Ọlọ́run Ísírẹ́lì, Olùgbàlà.+