- 
	                        
            
            Jeremáyà 2:23Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
- 
                            - 
                                        23 Báwo lo ṣe máa sọ pé, ‘Mi ò sọ ara mi di ẹlẹ́gbin. Mi ò sì tẹ̀ lé Báálì’? Wo ọ̀nà rẹ ní àfonífojì. Wo ohun tí o ti ṣe. O dà bí abo ọmọ ràkúnmí tó yára, Tó ń sá lọ sá bọ̀ ní ọ̀nà rẹ̀ láìsí ohun tó ń lé e, 
 
-