-
Jeremáyà 12:8Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
8 Ogún mi ti dà bíi kìnnìún inú igbó sí mi.
Ó ti bú mọ́ mi.
Ìdí nìyẹn tí mo fi kórìíra rẹ̀.
-
-
Ìdárò 5:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ńṣe lo kọ̀ wá sílẹ̀ pátápátá.
O ṣì ń bínú sí wa gidigidi.+
-