Ìsíkíẹ́lì 12:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 “Sọ pé, ‘Àmì ni mo jẹ́ fún yín.+ Ohun tí mo ṣe ni wọ́n á ṣe sí wọn. Wọn yóò lọ sí ìgbèkùn, wọ́n á kó wọn lẹ́rú.+
11 “Sọ pé, ‘Àmì ni mo jẹ́ fún yín.+ Ohun tí mo ṣe ni wọ́n á ṣe sí wọn. Wọn yóò lọ sí ìgbèkùn, wọ́n á kó wọn lẹ́rú.+