Léfítíkù 26:30 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 30 Èmi yóò run àwọn ibi gíga+ tí ẹ ti ń sin àwọn òrìṣà yín, màá wó àwọn pẹpẹ tùràrí yín lulẹ̀, màá sì to òkú yín jọ pelemọ sórí òkú àwọn òrìṣà ẹ̀gbin*+ yín, èmi* yóò pa yín tì, màá sì kórìíra yín.+ Sáàmù 106:38 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.
30 Èmi yóò run àwọn ibi gíga+ tí ẹ ti ń sin àwọn òrìṣà yín, màá wó àwọn pẹpẹ tùràrí yín lulẹ̀, màá sì to òkú yín jọ pelemọ sórí òkú àwọn òrìṣà ẹ̀gbin*+ yín, èmi* yóò pa yín tì, màá sì kórìíra yín.+
38 Wọ́n ń ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀,+Ẹ̀jẹ̀ àwọn ọmọkùnrin wọn àti ti àwọn ọmọbìnrin wọnTí wọ́n fi rúbọ sí àwọn òrìṣà Kénáánì;+Ilẹ̀ náà sì di ẹlẹ́gbin nítorí ìtàjẹ̀sílẹ̀.