ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Sáàmù 1:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  3 Ó máa dà bí igi tí a gbìn sétí odò,

      Tó ń so èso ní àsìkò rẹ̀,

      Tí ewé rẹ̀ kì í sì í rọ.

      Gbogbo ohun tó bá ń ṣe yóò máa yọrí sí rere.+

  • Sáàmù 92:12, 13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 12 Àmọ́ olódodo máa gbilẹ̀ bí igi ọ̀pẹ

      Wọ́n á sì tóbi bí igi kédárì ní Lẹ́bánónì.+

      13 Ilé Jèhófà ni a gbìn wọ́n sí;

      Wọ́n ń gbilẹ̀ ní àwọn àgbàlá Ọlọ́run wa.+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́