Jeremáyà 19:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Lọ ra ṣágo* amọ̀ lọ́dọ̀ amọ̀kòkò.+ Mú lára àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà àti lára àwọn àgbààgbà nínú àwọn àlùfáà,
19 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Lọ ra ṣágo* amọ̀ lọ́dọ̀ amọ̀kòkò.+ Mú lára àwọn àgbààgbà àwọn èèyàn náà àti lára àwọn àgbààgbà nínú àwọn àlùfáà,