Àìsáyà 1:16 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 16 Ẹ wẹ ara yín, ẹ jẹ́ kí ara yín mọ́;+Ẹ mú ìwà ibi yín kúrò níwájú mi;Ẹ jáwọ́ nínú ìwà burúkú.+ Ìsíkíẹ́lì 18:23 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 23 “‘Ǹjẹ́ inú mi máa ń dùn sí ikú ẹni burúkú?’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Ṣebí ohun tí mo fẹ́ ni pé kó yí ìwà rẹ̀ pa dà kó sì máa wà láàyè?’+
23 “‘Ǹjẹ́ inú mi máa ń dùn sí ikú ẹni burúkú?’+ ni Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ wí. ‘Ṣebí ohun tí mo fẹ́ ni pé kó yí ìwà rẹ̀ pa dà kó sì máa wà láàyè?’+