Diutarónómì 28:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 O máa di ohun tó ń dẹ́rù bani, ẹni ẹ̀gàn* àti ẹni ẹ̀sín láàárín gbogbo àwọn tí Jèhófà bá lé ọ lọ bá.+
37 O máa di ohun tó ń dẹ́rù bani, ẹni ẹ̀gàn* àti ẹni ẹ̀sín láàárín gbogbo àwọn tí Jèhófà bá lé ọ lọ bá.+