Sáàmù 35:4 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 4 Kí ìtìjú bá àwọn tó ń dọdẹ ẹ̀mí mi,* kí wọ́n sì tẹ́.+ Kí àwọn tó ń gbèrò láti pa mí sá pa dà nínú ìtìjú.
4 Kí ìtìjú bá àwọn tó ń dọdẹ ẹ̀mí mi,* kí wọ́n sì tẹ́.+ Kí àwọn tó ń gbèrò láti pa mí sá pa dà nínú ìtìjú.