ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 2:6
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  6 Torí o ti pa àwọn èèyàn rẹ, ilé Jékọ́bù tì.+

      Torí àwọn nǹkan tó wá láti Ìlà Oòrùn ti kún ọwọ́ wọn;

      Wọ́n ń pidán+ bí àwọn Filísínì,

      Àwọn ọmọ àjèjì sì pọ̀ láàárín wọn.

  • Jeremáyà 3:13
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 13 Kìkì pé kí o mọ ẹ̀bi rẹ lẹ́bi, nítorí o ti ṣọ̀tẹ̀ sí Jèhófà Ọlọ́run rẹ. Ò ń bá àwọn àjèjì* lò pọ̀ lábẹ́ gbogbo igi tó gbẹ̀rẹ̀gẹ̀jigẹ̀, àmọ́ o kò fetí sí ohùn mi,” ni Jèhófà wí.’”

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́