Jeremáyà 17:10 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 10 Èmi, Jèhófà, ń wá inú ọkàn,+Mo sì ń ṣàyẹ̀wò èrò inú,*Kí n lè san èrè fún ẹnì kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀Àti gẹ́gẹ́ bí èso iṣẹ́ rẹ̀.+
10 Èmi, Jèhófà, ń wá inú ọkàn,+Mo sì ń ṣàyẹ̀wò èrò inú,*Kí n lè san èrè fún ẹnì kọ̀ọ̀kan gẹ́gẹ́ bí ọ̀nà rẹ̀Àti gẹ́gẹ́ bí èso iṣẹ́ rẹ̀.+