Jóòbù 3:20 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 20 Kí ló dé tó fún ẹni tí ìyà ń jẹ ní ìmọ́lẹ̀,Tó sì fún àwọn tó ní ẹ̀dùn ọkàn*+ ní ìyè?