Jeremáyà 38:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 38 Ìgbà náà ni Ṣẹfatáyà ọmọ Mátánì, Gẹdaláyà ọmọ Páṣúrì, Júkálì+ ọmọ Ṣelemáyà àti Páṣúrì + ọmọ Málíkíjà gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé:
38 Ìgbà náà ni Ṣẹfatáyà ọmọ Mátánì, Gẹdaláyà ọmọ Páṣúrì, Júkálì+ ọmọ Ṣelemáyà àti Páṣúrì + ọmọ Málíkíjà gbọ́ ọ̀rọ̀ tí Jeremáyà ń sọ fún gbogbo àwọn èèyàn náà pé: