-
Jeremáyà 32:5Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 ‘Á mú Sedekáyà lọ sí Bábílónì, ibẹ̀ ló sì máa wà títí màá fi yíjú sí i,’ ni Jèhófà wí. ‘Bó tilẹ̀ jẹ́ pé ẹ̀ ń bá àwọn ará Kálídíà jà, ẹ kò ní borí.’”+
-