-
Jeremáyà 44:11Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
11 “Nítorí náà, ohun tí Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun, Ọlọ́run Ísírẹ́lì sọ nìyí, ‘Wò ó, mo ti pinnu láti mú àjálù bá yín kí n lè pa gbogbo Júdà run.
-