ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Àìsáyà 1:17
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 17 Ẹ kọ́ bí ẹ ṣe máa ṣe rere, ẹ wá ìdájọ́ òdodo,+

      Ẹ tọ́ àwọn aninilára sọ́nà;

      Ẹ gbèjà àwọn ọmọ aláìníbaba,*

      Kí ẹ sì gba ẹjọ́ opó rò.”+

  • Jeremáyà 22:3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 3 Ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ẹ máa dá ẹjọ́ bó ṣe tọ́, kí ẹ sì máa ṣe òdodo. Ẹ gba ẹni tí àwọn oníjìbìtì jà lólè sílẹ̀. Ẹ má ṣe ni àjèjì èyíkéyìí lára, ẹ má ṣèkà sí ọmọ aláìníbaba* èyíkéyìí tàbí opó.+ Ẹ má sì ta ẹ̀jẹ̀ aláìṣẹ̀ sílẹ̀ ní ibí yìí.+

  • Ìsíkíẹ́lì 22:29
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 29 Àwọn èèyàn ilẹ̀ náà ti lu jìbìtì, wọ́n sì ti jalè,+ wọ́n ti ni aláìní àti tálákà lára, wọ́n ti lu àjèjì ní jìbìtì, wọ́n sì ti fi ẹ̀tọ́ rẹ̀ dù ú.’

  • Míkà 2:2
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    •  2 Oko olóko wọ̀ wọ́n lójú, wọ́n sì gbà á;+

      Bẹ́ẹ̀ náà ni wọ́n gba ilé onílé;

      Wọ́n fi jìbìtì gba ilé mọ́ onílé lọ́wọ́,+

      Wọ́n gba ogún lọ́wọ́ ẹni tó ni ín.

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́