-
Ìsíkíẹ́lì 9:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
9 Lẹ́yìn náà, ó fi ohùn tó dún ketekete bá mi sọ̀rọ̀, ó ní: “Pe àwọn tí yóò fìyà jẹ ìlú náà wá, kí kálukú wọn mú ohun ìjà tó máa fi pa á run dání!”
-