1 Kíróníkà 3:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Àwọn ọmọ Jòsáyà ni Jóhánánì àkọ́bí, ìkejì ni Jèhóákímù,+ ìkẹta ni Sedekáyà,+ ìkẹrin ni Ṣálúmù. 2 Kíróníkà 36:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 36 Àwọn èèyàn ilẹ̀ náà mú Jèhóáhásì+ ọmọ Jòsáyà, wọ́n sì fi í jọba ní Jerúsálẹ́mù ní ipò bàbá rẹ̀.+