-
Jeremáyà 22:6Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
6 “Nítorí ohun tí Jèhófà sọ nípa ilé ọba Júdà nìyí,
‘Bíi Gílíádì lo rí sí mi,
Bí orí òkè Lẹ́bánónì.
Ṣùgbọ́n màá sọ ọ́ di aginjù;
Kò ní sí ọ̀kan nínú àwọn ìlú rẹ tó máa ṣeé gbé.+
-