Àìsáyà 2:12, 13 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 12 Torí ọjọ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni.+ Ó ń bọ̀ wá sórí gbogbo ẹni tó ń gbéra ga àti ẹni gíga,Sórí gbogbo èèyàn, ì báà jẹ́ ẹni gíga tàbí ẹni tó rẹlẹ̀,+13 Sórí gbogbo igi kédárì Lẹ́bánónì tó ga, tó sì ta yọÀti sórí gbogbo igi ràgàjì* Báṣánì,
12 Torí ọjọ́ Jèhófà Ọlọ́run àwọn ọmọ ogun ni.+ Ó ń bọ̀ wá sórí gbogbo ẹni tó ń gbéra ga àti ẹni gíga,Sórí gbogbo èèyàn, ì báà jẹ́ ẹni gíga tàbí ẹni tó rẹlẹ̀,+13 Sórí gbogbo igi kédárì Lẹ́bánónì tó ga, tó sì ta yọÀti sórí gbogbo igi ràgàjì* Báṣánì,