Diutarónómì 33:28 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 28 Ísírẹ́lì á máa gbé láìséwu,Orísun Jékọ́bù sì máa wà lọ́tọ̀,Ní ilẹ̀ tí ọkà àti wáìnì tuntun+ wà,Tí ìrì á máa sẹ̀ lójú ọ̀run rẹ̀.+ Jeremáyà 32:37 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 37 ‘Wò ó, màá kó wọn jọ láti inú gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí nínú ìbínú mi àti nínú ìrunú mi àti nínú ìkannú ńlá mi,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibí yìí láti máa gbé lábẹ́ ààbò.+ Sekaráyà 14:11 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 11 Àwọn èèyàn yóò gbé inú rẹ̀; kò tún ní sí ìparun tí ègún fà mọ́,+ wọn yóò sì máa gbé Jerúsálẹ́mù ní àlàáfíà.+
28 Ísírẹ́lì á máa gbé láìséwu,Orísun Jékọ́bù sì máa wà lọ́tọ̀,Ní ilẹ̀ tí ọkà àti wáìnì tuntun+ wà,Tí ìrì á máa sẹ̀ lójú ọ̀run rẹ̀.+
37 ‘Wò ó, màá kó wọn jọ láti inú gbogbo ilẹ̀ tí mo fọ́n wọn ká sí nínú ìbínú mi àti nínú ìrunú mi àti nínú ìkannú ńlá mi,+ màá sì mú wọn pa dà wá sí ibí yìí láti máa gbé lábẹ́ ààbò.+
11 Àwọn èèyàn yóò gbé inú rẹ̀; kò tún ní sí ìparun tí ègún fà mọ́,+ wọn yóò sì máa gbé Jerúsálẹ́mù ní àlàáfíà.+