-
Jeremáyà 16:14, 15Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
14 “‘Síbẹ̀, ìgbà kan ń bọ̀,’ ni Jèhófà wí, ‘tí wọn ò ní máa sọ pé: “Bí Jèhófà ti wà láàyè, ẹni tó mú àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ Íjíbítì!”+ 15 kàkà bẹ́ẹ̀, wọ́n á máa sọ pé: “Bí Jèhófà ti wà láàyè, ẹni tó mú àwọn èèyàn Ísírẹ́lì jáde kúrò ní ilẹ̀ àríwá àti gbogbo ilẹ̀ tó tú wọn ká sí!” màá sì mú wọn pa dà wá sí ilẹ̀ wọn, èyí tí mo fún àwọn baba ńlá wọn.’+
-