-
Jeremáyà 5:1Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
5 Ẹ lọ káàkiri àwọn ojú ọ̀nà Jerúsálẹ́mù.
Ẹ wò yí ká, kí ẹ sì kíyè sí i.
Ẹ wo àwọn ojúde rẹ̀
-
-
Jeremáyà 9:2Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
2 Ká ní mo ní ibi tí àwọn arìnrìn-àjò lè dé sí ní aginjù!
Mi ò bá fi àwọn èèyàn mi sílẹ̀, kí n sì kúrò lọ́dọ̀ wọn,
Nítorí alágbèrè ni gbogbo wọn,+
Àwùjọ àwọn oníbékebèke.
-