Àìsáyà 1:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Ibo la tún lè lù lára yín nígbà tí ẹ kò jáwọ́ nínú ìwà ọ̀tẹ̀ yín?+ Gbogbo orí yín ló ń ṣàìsànÀrùn sì ti kọ lu gbogbo ọkàn yín.+ Jeremáyà 5:3 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+ O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.* O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+ Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+Wọn kò sì yí pa dà.+ Sefanáyà 3:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Kò ṣègbọràn;+ kò gba ìbáwí.+ Kò gbẹ́kẹ̀ lé Jèhófà;+ kò sì sún mọ́ Ọlọ́run rẹ̀.+
5 Ibo la tún lè lù lára yín nígbà tí ẹ kò jáwọ́ nínú ìwà ọ̀tẹ̀ yín?+ Gbogbo orí yín ló ń ṣàìsànÀrùn sì ti kọ lu gbogbo ọkàn yín.+
3 Jèhófà, ǹjẹ́ kì í ṣe àwọn olóòótọ́ ni ojú rẹ ń wò?+ O lù wọ́n, ṣùgbọ́n wọn ò mọ̀ ọ́n lára.* O pa wọ́n run, àmọ́ wọn ò gba ìbáwí.+ Wọ́n mú ojú wọn le ju àpáta lọ,+Wọn kò sì yí pa dà.+