ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍNTÁNẸ́Ẹ̀TÌ ti Watchtower
ÀKÁ ÌWÉ ORÍ ÍŃTÁNẸ́Ẹ̀TÌ
ti Watchtower
Yorùbá
ọ́
  • ẹ
  • ọ
  • ṣ
  • ń
  • ẹ́
  • ẹ̀
  • ọ́
  • ọ̀
  • BÍBÉLÌ
  • ÌTẸ̀JÁDE
  • ÌPÀDÉ
  • Diutarónómì 18:20
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 20 “‘Tí wòlíì èyíkéyìí bá kọjá àyè* rẹ̀, tó sọ̀rọ̀ lórúkọ mi, ọ̀rọ̀ tí mi ò pa láṣẹ fún un pé kó sọ tàbí tó sọ̀rọ̀ lórúkọ àwọn ọlọ́run mìíràn, wòlíì yẹn gbọ́dọ̀ kú.+

  • Jeremáyà 14:15
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 15 Nítorí náà, ohun tí Jèhófà sọ nìyí: ‘Ní ti àwọn wòlíì tó ń sọ tẹ́lẹ̀ ní orúkọ mi, bó tilẹ̀ jẹ pé mi ò rán wọn, tí wọ́n ń sọ pé idà tàbí ìyàn kò ní wáyé ní ilẹ̀ yìí, idà àti ìyàn ni yóò pa àwọn wòlíì náà.+

  • Ìsíkíẹ́lì 13:2, 3
    Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
    • 2 “Ọmọ èèyàn, sọ àsọtẹ́lẹ̀ sórí àwọn wòlíì Ísírẹ́lì,+ kí o sì sọ fún àwọn tó ń hùmọ̀ àsọtẹ́lẹ̀ tiwọn* pé,+ ‘Ẹ gbọ́ ọ̀rọ̀ Jèhófà. 3 Ohun tí Jèhófà Olúwa Ọba Aláṣẹ sọ nìyí: “Ẹ gbé, ẹ̀yin òmùgọ̀ wòlíì, tí ẹ̀ ń sọ èrò ọkàn yín, láìrí nǹkan kan!+

Yorùbá Publications (1987-2025)
Jáde
Wọlé
  • Yorùbá
  • Fi Ráńṣẹ́
  • Èyí tí mo fẹ́ràn jù
  • Copyright © 2025 Watch Tower Bible and Tract Society of Pennsylvania
  • Àdéhùn Nípa Lílò
  • Òfin
  • Ètò Nípa Ìsọfúnni Rẹ
  • JW.ORG
  • Wọlé
Fi Ráńṣẹ́