Diutarónómì 32:15 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.
15 Nígbà tí Jéṣúrúnì* sanra tán, ó di ọlọ̀tẹ̀, ó sì ń tàpá. O ti sanra, o ti ki, o sì ti kún.+ Ó wá pa Ọlọ́run tì, ẹni tó dá a,+Ó sì fojú àbùkù wo Àpáta ìgbàlà rẹ̀.