-
Jeremáyà 26:4Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
4 Sọ fún wọn pé: “Ohun tí Jèhófà sọ nìyí, ‘Bí ẹ kò bá fetí sí mi láti máa tẹ̀ lé òfin* mi tí mo fún yín,
-
-
Jeremáyà 29:22Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun
-
-
22 Ohun tó ṣẹlẹ̀ sí wọn á di ohun tí gbogbo àwọn ará Júdà tó wà ní ìgbèkùn ní Bábílónì á máa sọ, tí wọ́n bá fẹ́ gégùn-ún fún àwọn èèyàn, wọ́n á ní: “Kí Jèhófà ṣe ọ́ bíi Sedekáyà àti Áhábù, àwọn tí ọba Bábílónì yan nínú iná!”
-