Jeremáyà 1:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Jèhófà bá a sọ̀rọ̀ nígbà ayé Jòsáyà+ ọmọ Ámọ́nì,+ ọba Júdà, ní ọdún kẹtàlá tó ti ń jọba.