Jeremáyà 29:19 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 19 nítorí wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ mi, tí mo fi ránṣẹ́ sí wọn nípasẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ mi wòlíì,’ ni Jèhófà wí, ‘tí mò ń rán wọn léraléra.’*+ “‘Ṣùgbọ́n ẹ kò fetí sílẹ̀,’+ ni Jèhófà wí.
19 nítorí wọn kò fetí sí ọ̀rọ̀ mi, tí mo fi ránṣẹ́ sí wọn nípasẹ̀ àwọn ìránṣẹ́ mi wòlíì,’ ni Jèhófà wí, ‘tí mò ń rán wọn léraléra.’*+ “‘Ṣùgbọ́n ẹ kò fetí sílẹ̀,’+ ni Jèhófà wí.