Àìsáyà 14:2 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 2 Àwọn èèyàn máa mú wọn, wọ́n á mú wọn wá sí àyè wọn, ilé Ísírẹ́lì sì máa fi wọ́n ṣe ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin+ ní ilẹ̀ Jèhófà; wọ́n máa mú àwọn tó mú wọn lẹ́rú, wọ́n sì máa di olórí àwọn tó fipá kó wọn ṣiṣẹ́. Hábákúkù 2:8 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 8 Torí ìwọ náà ti kó ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè lẹ́rù,Gbogbo èèyàn yóò kó ọ lẹ́rù,+Nítorí ẹ̀jẹ̀ àwọn èèyàn tí o ta sílẹ̀ Àti ìwà ipá tí o hù sí ayé,Sí àwọn ìlú àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+
2 Àwọn èèyàn máa mú wọn, wọ́n á mú wọn wá sí àyè wọn, ilé Ísírẹ́lì sì máa fi wọ́n ṣe ẹrúkùnrin àti ẹrúbìnrin+ ní ilẹ̀ Jèhófà; wọ́n máa mú àwọn tó mú wọn lẹ́rú, wọ́n sì máa di olórí àwọn tó fipá kó wọn ṣiṣẹ́.
8 Torí ìwọ náà ti kó ọ̀pọ̀ orílẹ̀-èdè lẹ́rù,Gbogbo èèyàn yóò kó ọ lẹ́rù,+Nítorí ẹ̀jẹ̀ àwọn èèyàn tí o ta sílẹ̀ Àti ìwà ipá tí o hù sí ayé,Sí àwọn ìlú àti àwọn tó ń gbé inú wọn.+