Jeremáyà 47:5 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 5 Orí pípá* máa dé bá Gásà. A ti pa Áṣíkẹ́lónì lẹ́nu mọ́.+ Ìwọ àṣẹ́kù àfonífojì* wọn,Ìgbà wo lo máa kọ ara rẹ lábẹ dà?+
5 Orí pípá* máa dé bá Gásà. A ti pa Áṣíkẹ́lónì lẹ́nu mọ́.+ Ìwọ àṣẹ́kù àfonífojì* wọn,Ìgbà wo lo máa kọ ara rẹ lábẹ dà?+