Jeremáyà 49:1 Bíbélì Mímọ́ ti Ìtumọ̀ Ayé Tuntun 49 Sí àwọn ọmọ Ámónì,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ṣé Ísírẹ́lì kò ní ọmọ ni? Ṣé kò ní ẹni tó máa jogún rẹ̀ ni? Kí ló dé tí Málíkámù+ fi gba Gádì?+ Tí àwọn èèyàn rẹ̀ sì ń gbé inú àwọn ìlú Ísírẹ́lì?”
49 Sí àwọn ọmọ Ámónì,+ ohun tí Jèhófà sọ nìyí: “Ṣé Ísírẹ́lì kò ní ọmọ ni? Ṣé kò ní ẹni tó máa jogún rẹ̀ ni? Kí ló dé tí Málíkámù+ fi gba Gádì?+ Tí àwọn èèyàn rẹ̀ sì ń gbé inú àwọn ìlú Ísírẹ́lì?”